Bukunmi Oluwashina jẹ́ òṣèrébìnrin[1] [2] àti olóòtú sinimá àgbéléwò, ọmọ Oke-Imesi ní ìpínlẹ̀ Ekiti lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3][4]

Bukunmi Oluwashina
Ọjọ́ìbí7 Oṣù Kaarun
Oke-Imesi, Ekiti State
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaObafemi Awolowo University
Iṣẹ́
  • òṣèrébìnrin
  • olóòtú sinimá

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Bukunmi Oluwashina jẹ́ ọmọ keta nínu ọmọ meje tí àwọn òbí rẹ̀ bí.[5]Ó lọ sí Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ níbi tó ti gba oyè nínu ere ori itage.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Olaniran, Mariam (October 21, 2021). "Bukunmi Oluwashina surprises best friend with N2m cash on birthday - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper. Retrieved May 21, 2022. 
  2. "Why I kept my daughter away from social media –Bukunmi Oluwasina". Punch Newspapers. 2022-03-04. Retrieved 2022-05-21. 
  3. "Bukunmi Oluwashina: Biography, Age, Songs, Movies, Family & Career". Nigerian Finder. 2019-01-24. Retrieved 2022-05-21. 
  4. Odimayo, Kelechi (2020-11-19). "Bukunmi Oluwashina's biography and amazing career". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2022-05-21. 
  5. "Bukunmi Oluwasina: Who be dis Nigerian actress wey her love tori totori Nigerians". BBC News Pidgin. 2020-09-17. Retrieved 2022-05-21. 
  6. Africa, Information Guide (October 24, 2020). "Bukunmi Oluwashina Biography, Age, Early Life, Family, Education, Career And Net Worth ~ Information Guide Africa". Information Guide Africa. Retrieved May 21, 2022.