Busoogi
BUSHOOG
Bushoog ni a mọ èdè yìí sí. Bákan náà ni wọ́n tún ń jẹ́. Bamong, Bushong, Bushongo, Busoong, Ganga, Kuba Mbale, Mongo Shongo.
Wọ́n jẹ mọ ẹka èdè ti Djeenbe, Ngende, Ngombe, Ngombia, Ngongo, panga, Pianga, Shoba, Shobuia ìsobwa.
Èdè náà tì wà títí dí oni lápá ijọba onimira ilẹ Congo. Bakan náà ni wọ́n jẹ́ ẹbi Niger-Congo ní ọ̀wọ́ ti Bushong. Awọn èèyàn tó n ṣọ wọ́n sì ju ẹgbàágbèje lọ.