Busta Rhymes
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Trevor George Smith Jr.[3][4][5][6] (ọjọ́ìbí May 20, 1972), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí-ìtàgé rẹ̀ Busta Rhymes, ni olórin rap, olórin, akọrin, olóòtú àwo-orin, onígbàjámọ̀ àwọ-orin, àti òṣeré ará Amẹ́ríkà. Chuck D láti ẹgbẹ́ olórin rap, Public Enemy ló sọ ọ́ lorúkọ báhun.
Busta Rhymes | |
---|---|
Busta performing in 2015 | |
Ọjọ́ìbí | Trevor George Smith Jr. 20 Oṣù Kàrún 1972[1] New York City, New York, U.S. |
Orúkọ míràn | Trevor Taheim Smith |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1990–present[2] |
Awards | List of awards and nominations |
Musical career | |
Irú orin | Hip hop |
Labels | |
Associated acts | |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Monitor". Entertainment Weekly (1260): 34. May 24, 2013.
- ↑ John Bush. "Busta Rhymes". AllMusic. Retrieved November 23, 2019.
- ↑ "Busta Rhymes must be released, orders judge". The Daily Telegraph. https://www.telegraph.co.uk/news/uknews/3081767/Busta-Rhymes-must-be-released-orders-judge.html. Retrieved March 23, 2016.
- ↑ Gonzalez, Victor. "Rick Ross, Pitbull, and Other Rappers' Paternity Suits". Miami New Times. http://www.miaminewtimes.com/music/rick-ross-pitbull-and-other-rappers-paternity-suits-6386723. Retrieved March 23, 2016.
- ↑ "Buzz Briefs: Emilio Navaira, David Blaine". CBS News. Retrieved March 23, 2016.
- ↑ "Busta Rhymes Refused Entry into Britain". Accesshollywood.com. NBCUniversal, Inc. Retrieved March 23, 2016.