CERN
Coordinates: 46°14′03″N 6°03′10″E / 46.23417°N 6.05278°E
CERN tàbí European Organization for Nuclear Research (Faransé: Organisation européenne pour la recherche nucléaire), lasan bi CERN tabi Cern ( /ˈsɝn/; ìpè Faransé: [sɛʁn]; e wo Ìtàn) jẹ́ àgbájọ akáríayé tí iṣẹ́ rẹ̀ ni láti bòjúsí ìṣeṣẹ́ ilé-àdánwò físíksì eruku tóbijùlọ lágbàáyé, tó wà ní àríwáìwọ̀òrùn àdúgbò Geneva ní ẹ̀bá bodè Fránsì àti Swítsàlandì (46°14′3″N 6°3′19″E / 46.23417°N 6.05528°E). Ó jé dídásílẹ̀ ní 1954, àgbájọ náà ní orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ Europe 20.
European Organization for Nuclear Research Organisation européenne pour la recherche nucléaire | |
---|---|
Àwọn orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ | |
Ìdásílẹ̀ | 29 September 1954[1] |
Ibùjókòó | Geneva, Switzerland |
Ọmọẹgbẹ́ | Àwọn orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ 21 àti abẹ̀wò 7 |
Olùdarí Àgbà | Fabiola Gianotti |
Website | cern.ch |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedfoundation