Carl 16k Gustaf ilẹ̀ Swídìn
Carl Kerindinlogun Gustaf (oruko abiso: Carl Gustaf Folke Hubertus, ojoibi 30 April 1946) lo je Oba ile Swidin lati 15 September 1973, nigbati baba-baba re Gustaf Kefa Adolf ku. Ohun nikan ni omokunrin baba re Prince Gustaf Adolf, Duke of Västerbotten to sologbe , ati iya re Princess Sibylla of Saxe-Coburg and Gotha. Baba re Gustaf Adolf ku ninu ijamba baalu losan ojo 26 January 1947, ni Papa Oko-ofurufu Copenhagen ni Denmark.
Carl 16k Gustaf Carl XVI Gustaf | |
---|---|
King Carl XVI Gustaf in Tallinn, Estonia (2023) | |
Reign | 15 September 1973 – present |
Enthronement | 19 September 1973 |
Predecessor | Gustaf VI Adolf |
Heir apparent | Crown Princess Victoria |
Consort | Queen Silvia, nee Sommerlath |
Issue | |
Victoria, Crown Princess of Sweden Prince Carl Philip, Duke of Värmland Princess Madeleine, Duchess of Hälsingland and Gästrikland | |
Full name | |
Carl Gustaf Folke Hubertus | |
House | House of Bernadotte |
Father | Prince Gustav Adolf, Duke of Västerbotten |
Mother | Princess Sibylla of Saxe-Coburg and Gotha |
Religion | Lutheran (Church of Sweden) |
Unlike many other European monarchs who have extensive styles, King Carl Gustaf's formal and complete style is simply His Majesty Carl XVI Gustaf, King of Sweden. The King's heir apparent, upon passage on 1 January 1980 of a new law establishing equal primogeniture (the first such law passed in European history), is Crown Princess Victoria, the eldest child of the King and his wife, Queen Silvia.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |