Carla Gugino

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Carla Gugino ( /ɡʊˈn/ guu-JEE-noh; tí a bí ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1971) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè Amẹ́ríkà. Lẹ́yìn ìgbà tí ó farahàn nínú eré Troop Beverly Hills (1989) àti This Boy's Life (1993), ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Ingrid Cortez nínú eré Spy Kids (2001–2003), Rebecca Hutman nínú Night at the Museum (2006), Laurie Roberts nínú American Gangster (2007), Det. Karen Corelli nínú Righteous Kill (2008), Dr. Alex Friedman nínú Race to Witch Mountain (2009), Sally Jupiter in Watchmen (2009), Dr. Vera Gorski nínú Sucker Punch (2011), Amanda Popper nínú Mr. Popper's Penguins (2011), Emma Gaines nínú San Andreas (2015), àti gẹ́gẹ́ bi Jessie Burlingame nínú Gerald's Game (2017).

Carla Gugino
Gugino ní ọdún 2013
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kẹjọ 1971 (1971-08-29) (ọmọ ọdún 53)
Sarasota, Florida, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1988–present
Alábàálòpọ̀Sebastián Gutiérrez (1996–present)
Àwọn olùbátanCarol Merrill (aunt)

Gugino tún kó ipa nínú eré the Karen Sisco (2003), Threshold (2005–2006), The Haunting of Hill House (2018), nínú Jett (2019), ó sì tún farahàn nínú The Haunting of Bly Manor (2020).