Carlos Fuentes
Carlos Fuentes Macías (ojoibi November 11, 1928) je olukowe ara Meksiko ati ikan ninu awon olukodun ati akoayoka to gbajumojulo ni ibi awon elede Spani. O nipa lori Onaikowe Latini Amerika onigbakanna, be sini awon iwe re ti je yiyilededa si opo ede lagbaye.
Carlos Fuentes Macías | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | 11 Oṣù Kọkànlá 1928 Panama City, Panama |
Iṣẹ́ | novelist, writer |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Mexican |
Ìgbà | 1954 – |
Literary movement | Latin American Boom |
Notable works | The Death of Artemio Cruz (1962) The Old Gringo (1985) |
Spouse | Rita Macedo (1959–1973) Silvia Lemus (1976–) |
Children | Cecilia Fuentes Macedo (1962- ), Carlos Fuentes Lemus (1973-1999), Natasha Fuentes Lemus (1976-2005) |
Website | |
[1] |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |