Carlyle Glean

Sir Carlyle Arnold Glean, GCMG[1] je oloselu ati Gomina Agba orile-ede Grenada. O je Alakoso Eto Eko ni igba ijoba Nicholas Brathwaite lati 1990 titi di 1995. Won yan sipo Gomina Agba ni November 2008.


Sir Carlyle Green

Governor General of Grenada
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
27 November 2008
MonarchElizabeth II
Alákóso ÀgbàTillman Thomas
AsíwájúDaniel Williams


ItokasiÀtúnṣe