Caroll Spinney

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Caroll Edwin Spinney tí a bí lọjọ́ merindinlogbon, oṣù kejila ọdún 1933,dágbére fáyé ní Ọjọ́ kejo oṣù kejila ọdún 2019 (December 26, 1933- December 8 2019)[1][2] jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.

Caroll Spinney
Ọjọ́ìbí(1933-12-26)Oṣù Kejìlá 26, 1933
Waltham, Massachusetts, USA
Aláìsí(2019-12-08)Oṣù Kejìlá 8, 2019
Woodstock, Connecticut, USA
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmẹ́ríkà
Iṣẹ́
  • Actor
  • Writer
Olólùfẹ́
  • Debra Spinney
  • Janice Spinney

Àwọn ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Caroll Spinney". IMDb. 1933-12-26. Retrieved 2022-05-05. 
  2. "Caroll Spinney, Big Bird’s Alter Ego on ‘Sesame Street,’ Is Dead at 85". The New York Times. 2019-12-08. Retrieved 2022-05-05.