Caty Louette
Caty Louette tabi Cathy Louet (1713-d. lẹyin 1776) jẹ oniṣowo pataki ti ilẹ Afrika. Caty jẹ ọkan lara awọn eniyan jakan ni agbegbe ti Gorèe. Caty Louette jẹ̀ ọmọbinrin arakunrin to wa lati ilẹ French Nicolas Louët, to jẹ oṣiṣẹ ilẹ̀ french ti east india ati mistress rẹ Caty de Rufisque ti Gorèe[1][2].
Louette di signare-consort ti Pierre Aussenac de Carcassone ti ilẹ french, óṣiṣẹ ti East India ti ilẹ French[3]. Caty Louette jẹ gbajumọ oniṣowo ẹru ti Gorèe[4]. Caty le kọ ati ka, eyi lo mu ko jẹ obinrin to lowo gidi gan to si ni oko ẹru to tobijulọ ni 1767[5]. Caty ni ẹru 68 nibi awọn oniṣowo ẹru ti ma nta awọn ẹru kaki wọn fiwọn pamọ[6].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ Aidoo, Theodora (2019-09-09). "5 little-known black female slave traders who changed the course of history - Page 5 of 6". Face2Face Africa. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ "Notorious Atlantic African Slave Traders – Atlantic Processes From Africa's Perspective". Atlantic Processes From Africa's Perspective – Connecting The World And It's Diaspora To An Emerging Creator. 2023-05-04. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ "5 Little-Known Black Female Slave Traders Who Changed The Course Of History". How Africa News. 2022-09-14. Archived from the original on 2023-08-25. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ "Caty Louette, the most Powerful Female Slave Trader in Senegal’s Gorée Island in the 1800s". Blogarama. 2021-08-10. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ Hinchman, M. (2015) (in fr). Portrait of an Island: The Architecture and Material Culture of Gorée, Sénégal, 1758–1837. Early Modern Cultural Studies. Nebraska. p. 94. ISBN 978-0-8032-5413-8. https://books.google.com.ng/books?id=zmUoDwAAQBAJ&pg=PA94. Retrieved 2023-08-25.
- ↑ Hir, M.P.L. (2022). French Immigrants and Pioneers in the Making of America. McFarland, Incorporated, Publishers. p. 229. ISBN 978-1-4766-4485-1. https://books.google.com.ng/books?id=nNljEAAAQBAJ&pg=PA229. Retrieved 2023-08-25.