Cecilia Zoppelletto
Cecilia Zoppelletto jẹ́ olùdarí eré lóbìnrin àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Itálíà.[1][2] Ó gbajúmọ̀ fún dídarí eré ìtàn-àkọọ́lẹ̀ kan lórílẹ̀-èdè Kóngò, èyí tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ La Belle At The Movies.[3]
Cecilia Zoppelletto | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Cecilia Zoppelletto Padua, Italy |
Orílẹ̀-èdè | Italian |
Iṣẹ́ | Director, producer, screenwriter, lecturer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2014–present |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Cecilia Zoppelletto". African Filmny. Retrieved 30 October 2020.
- ↑ "Cecilia Zoppelletto: DIRECTOR, SCREENWRITER, PRODUCER". MUBI. Retrieved 30 October 2020.
- ↑ "Interviewing Cecilia Zoppelletto on ‘La Belle at the Movies’". qmunicatemagazine. Archived from the original on 10 November 2021. Retrieved 30 October 2020.