Celeste Ntuli
Celeste Ntuli (bíi ni kẹẹdọgbọn oṣù kẹjọ ọdún 1978) jẹ́ òṣèré àti aláwàdà ní orílẹ̀ èdè South Áfríkà[1]. Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí olòrì fún ẹ̀fẹ̀ ni ilẹ̀ Zulu.[2][3][4][5]
Celeste Ntuli | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kẹjọ 1978 Empangeni, KwaZulu-Natal, South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Iléẹ̀kọ́ gíga | DUT |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún | Isibaya |
Wọ́n bíi Ntuli ni ìlú Empangeni níbi ó ti gba ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀. Òun ni ọmọ kẹfà láàrín àwọn ọmọ mẹjọ tí àwọn òbí rẹ bí.[6] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Durban University of Technology.[7]
Iṣẹ́
àtúnṣeNí ọdún 2005, ó ṣe ẹ̀fẹ̀ àkókò rẹ ni ilé ìjọsìn ni Durban. Ó to ṣe orisirisi ẹ̀fẹ̀, láàrin àwọn ayẹyẹ tí ó ti se ẹ̀fẹ̀ ni Blacks Only comedy showcase ní ọdún 2010 àti 2012, SA Comic’s Choice Awards 2012. Ó ti kopa ninu awọn eré bíi[8] Isibaya, 10 Days in Sun City, Lockdown, Looking For Love àti Trippin with Skhumba. Ní ọdún 2014, ó gbà àmì ẹ̀yẹ Best Supporting Actress láti odo Golden Horn Award[9]. Ní ọdún 2018, wọn yàán fún orisirisi àmì ẹ̀yẹ láti ọ̀dọ̀ Comics' Choice Awards.[10][11] Ó gbà àmì ẹ̀yẹ Flying Solo àti Comedy G Award láti ọ̀dọ̀ Savanna Comics Choice Awards.[12][13][14][15][16]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "PICS: CELESTE NTULI WORKING ON HER TRANSFORMATION!". DailySun. Retrieved 2019-12-11.
- ↑ Makena, Kevin (2019-08-22). "Celeste Ntuli biography: age, child, husband, siblings, comedy and more". Briefly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "Celeste Ntuli | TVSA". www.tvsa.co.za. Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "WATCH: Celeste Ntuli works up a sweat at the gym". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-01. Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "Celeste Ntuli". Elegant Entertainment. Archived from the original on 2019-05-17. Retrieved 2019-12-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Trippin’ With Skhumba: What you need to know about Celeste Ntuli". The South African (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-21. Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "Celeste Ntuli". Whacked. Retrieved 2019-12-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Celeste Ntuli on acting: I never felt like I fitted in". TimesLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "Celeste Ntuli". Cape Town Comedy Club (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-11. Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "Celeste Ntuli and Skhumba Hlophe top Comics Choice Awards noms | IOL Entertainment". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "Skhumba and Celeste Ntuli top Comic Choice Award nominations". SowetanLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-11.
- ↑ Herbst, Denika (2019-09-09). "Celeste Ntuli bags not 1 but 2 Savanna Comics' Choice Awards". Briefly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-11. Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "All the 2019 winners of the Savanna Comics' Choice Awards". www.bizcommunity.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-11.
- ↑ Coetzee, Nikita (2019-09-08). "Savanna Comics' Choice Awards crowns the top comedian in SA - Here are all the winners". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-11.
- ↑ "Winners 2019 | South Africa | Savanna Comics' Choice Awards". comicschoice (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-11. Retrieved 2019-12-11.
- ↑ reporter, Citizen. "Loyiso Gola wins Comic of the Year at Comics’ Choice Awards". The Citizen (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-11.