Celestina Onyeka
Celestina Onyeka jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15, óṣu july ni ọdun 1984. Agbabọọlu naa ṣere fun Pelican Stars gẹgẹbi defender[1][2][3].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 15 Oṣù Keje 1984 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2004 | Pelican Stars | ||
National team | |||
2004 | Nigeria women's national football team | 0 (?) | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Celestina kopa ninu Olympic to waye ni ọdun 2004 nibi ti o ti jẹ okan lara team awọn obinrin ilẹ naigiria ti apapọ[4].