Charles Augustin de Coulomb
(Àtúnjúwe láti Charles-Augustin de Coulomb)
Charles-Augustin de Coulomb (14 September 1736 – 23 August 1806) je asefisiksi ara Fransi. O gbajumo fun gbigbedide ofin Coulomb, itumo agbara iwalojukanonina (electrostatic force) lati se ifamora ati isunsoun. Eyo SI agbara eru (charge), coulomb, wa lati inu oruko re.
Charles-Auguston de Coulomb | |
---|---|
Portrait by Hippolyte Lecomte | |
Ìbí | Angoulême, France | 14 Oṣù Kẹ̀sán 1736 invalid month
Aláìsí | 23 August 1806 Paris, France | (ọmọ ọdún 70)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | French |
Pápá | Physics |
Ó gbajúmọ̀ fún | Coulomb's law |
Religious stance | Roman Catholic |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |