Charles Olúmọ
Charles Olúmọ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àgbákò ṣùgbọ́n tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Abudul Salam Sànyàolú (ti a bi ni Oṣu Keje ọdun 1923 o si ku ni Oṣu Kẹwa Ọjọ 31, Ọdun 2024) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Nínú sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá tí ó jẹ́ abala Nollywood ni ó ti gbajúmọ̀.
Charles Olúmọ | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Abudul Salam Sànyàolú |
Orúkọ míràn | Àgbákò |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Osere |
Iṣẹ́ tíátà rẹ̀
àtúnṣeÀgbákò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1953 ní ilé ìjọsìn, The Apostolic Church ni ìpínlẹ̀ Èkó.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí ìta
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "My Father used charm on me to make me lose interest in Acting – Charles Olumo Agbako". Sahara Weekley. 2015-10-27. Retrieved 22 January 2017.