Charly Boy
Oníwé-Ìròyín
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the Nigerian singer. Fún the American rapper, ẹ wo: Chalie Boy.
Charly Boy | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Charles Chukwuemeka Oputa |
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kẹfà 1950 Port Harcourt, Nigeria |
Irú orin | Afro pop, Afrobeat, highlife |
Occupation(s) | Singer-songwriter, journalist, producer, Idol series judge |
Years active | 1982–present |
Associated acts | Dr. Alban Diane 'Lady Di' Oputa Duchess Maria |
Charly Boy, tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Charles Chukwuemeka Oputa, ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹ̀fà ọdún 1950[1] (ó tún ń jẹ́ CB, His Royal Punkness, àti
Area Fada),[2]akọrin àti olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olùkọ́ni lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán, atèwé-ìròyìnjade, àti àṣàgbéjáde. Ọ̀kan jùlọ ní orílè-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ oǹṣe àríyá aláríyànjiyàn, ó di mímọ̀ tí ó dára jùlọ nípa iṣẹ́ ẹ rẹ̀ fún yíyan ìgbésí ayé e rẹ̀, òṣèlú wíwò, àti oǹṣe ìgbéròhìnjáde,tí a mọ̀ jùlọ sí The Charly Boy Show. Ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i Ààrẹ ti Performing Musicians Association of Nigeria, àti ní ọdún 2011 ó jẹ́ Idol Series onídàájọ́.
- ↑ PHOTO: Charly Boy Fully Uncloth**Turns 61 Today Archived 22 June 2012 at the Wayback Machine.
- ↑ "Charly Boy heads to Buddha temple". News2.onlinenigeria.com. Archived from the original on 9 August 2016. Retrieved 5 January 2012.