Charlyne Brumskine
Charlyne M. Brumskine jẹ́ olóṣèlú tí orílẹ̀-èdè Liberia, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ onínúure.[1] Òun ni adarí ẹgbẹ́ olóṣèlú ti Liberty Party.[2]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeBrumskine jẹ́ ọmọ Bassa ní orílẹ̀-èdè Liberia, tí ó wá láti Buchanan, Grand Bassa County àti Yekepa, ní Nimba County. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Howard University School of Law ní Washington D.C. àti ní Barnard College ní New York.[3] Bákan náà, ó gba oyè ẹ̀kọ́ láti Louis Arthur Grimes School of Law.[4]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeBrumskine jẹ́ káńsẹ́lọ̀ ní ìlú Buchanan, ní Liberia.[5] Òun ni igbá-kejì ti ẹgbẹ́ Collaborating Political Parties.[6]
Lásìkò ìdìbò ọdún 2023 ti Liberia, òun ni olùdíje dupò Ààrẹ pẹ̀lú olùdíje ti ọmọ-ẹgbẹ́ Alternative National Congress, ìyẹn Alexander B. Cummings Jr.[7]
Ìgbésí ayé ara ẹni
àtúnṣeBrumskine ni ọmọbìnrin Charles Brumskine, tó jẹ́ olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Liberty Party àti ẹgbẹ́ President Pro Tempore of the Senate of Liberia.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Boayue, Francis G. (2023-09-12). "CPP Vice Standard-Bearer Charlyne Brumskine Rally Liberians in District 6 to Support Martin Saye Kollah Representative Bid". FrontPageAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-19.
- ↑ "LIBERTY PARTY - Reconciliation Speech by Charlyne Brumskine". Analyst Liberia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-22. Retrieved 2023-09-19.
- ↑ Dakpannah 24 (2023-05-18). "Cllr. Charlyne M. Brumskine: A Legal Luminary, Philanthropist, and Champion of Gender Rights – Dakpannah24" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-19.
- ↑ Writer, Contributing (2023-09-07). "Meet Cllr. Charlyne M. Brumskine: Liberia's Legal Luminary and Compassionate Humanitarian Bringing Transformation and Hope". FrontPageAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-19.
- ↑ 5.0 5.1 Clayeh, J. H. Webster (2022-12-13). "Liberia: Charlyne Brumskine Petitioned for Legislative Seat, Following Late Father’s Footsteps". FrontPageAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-19.
- ↑ "Liberia: 'Pres. Weah Has Enslaved You' - CPP Vice Standard-Bearer Cllr. Charlyne Brumskine Asserts At Intellectual Forum" (in en). FrontPageAfrica. 2023-09-07. https://allafrica.com/stories/202309070455.html.
- ↑ "Issues". ANC-Global. Retrieved 2023-08-03.