Chemtou Museum
Chemtou Museum jẹ́ musíọ́mù kan tí ó wà ní Chemtou, orílẹ̀ èdè Tunisia. Tunisian National Heritage Institute àti German Archaeological Institute tí ọ́fícì wọn wà ní Rome, Italy ló da kalẹ̀.[1] Ó wà ní agbègbè ìlú old Roman ní Simmithu, ní ẹgbẹ́ ibi tí wọ́n ti ń wa kùṣà mábù ní ibi tí ìjọba Berber ní Numidia ní ayé àtijọ́.[2]
Chemtou Museum | |
---|---|
ẹnu ọ̀nà Chemtou Museum | |
Building | |
Location | Chemtou, Tunisia |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ ARTESSERE. "Art Places – Chemtou Museum, Tunisia". ARTESSERE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-02-28. Retrieved 2023-02-28.
- ↑ "Explore The Chemtou Museum". Attenvo (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-28.