Chi-Chi Igbo jẹ agbabọọlu orilẹ́ ede naigiria ti a bini 1, óṣu May ni ọdun 1986. Chi-Chi jẹ elere super falcons tẹleri, arabinrin naa ṣere gẹgẹbi ipo forward fun Fortuna Hjørring[1][2][3]

Chi-Chi Igbo
Personal information
OrúkọChi-chi Igbo
Ọjọ́ ìbí1 Oṣù Kàrún 1986 (1986-05-01) (ọmọ ọdún 38)
Ibi ọjọ́ibíIsiochi, Abia state
Ìga1.63m
Playing positionForward
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2002–2016Fortuna Hjørring270
National team
2004–2010Nigeria
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Agbabọọlu naa kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 2007 to waye ni china[4].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/chi-chi-igbo_prs333629/person.shtml
  2. https://fbref.com/en/players/38e15111/Chi-Chi-Igbo
  3. https://ng.soccerway.com/players/chi-chi-igbo/19454/
  4. https://www.worldfootball.net/player_summary/chichi-igbo/frauen-wm/4/