Chike Obi /θj/ (April 17, 1921 – March 13, 2008) jẹ́ Olóṣèlú, Onímọ̀ Mátì àti ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ orílẹ̀ ède Nàìjíríà nígbà ayé rẹ̀.[1] Chike Obi ni ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ láti gba àmì ẹ̀yẹ Dókítà nínú ìmọ̀ mátì.[2] Obi ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé àti journals nípa Mátì àti ìṣèlú ní Nàìjíríà.[3]

Chike Obi
Ọjọ́ ìbíApril 17, 1921
Anambra State, Nigeria
Ọjọ́ aláìsíMarch 13, 2008 (2008-03-14) (ọmọ ọdún 86)
Iṣẹ́Mathematician
CitizenshipỌmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíría
Notable awardsSigvard Eklund Prize
SpouseBelinda (w. 2009)
Children4

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Obi lọ ìwé ní oríṣi àgbègbè ní Nàìjíríà kí ó tó kàwé nípa ìmọ̀ MátìYunifásítì London.[4] Ní kété tí ó gba àmì ẹyẹ degree àkọ́kọ́, a fun ní ànfàní ọ̀fẹ́ láti ṣe ìwádìí ní Pembroke College, Cambridge, lẹ́yìn náà, tí ó kàwé gboyè Dókítà ní Massachusetts Institute of Technology[5] ti Cambridge, Massachusetts, Orílẹ̀ èdè America, èyí tí ó sọ ọ́ di ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ láti gba àmì ẹyẹ Dókítà nínú ìmọ̀ Mátì.[6]

Lẹ́yìn ikú rẹ̀

àtúnṣe

Obi fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 2008, ìyàwó rẹ̀, Belinda, ẹni tí ó jẹ́ Nursì náà fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 2010, àwọn méjèèjì fi ọmọ mẹ́rin sáyé.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Obituary: Chike Obi". www.thenewblackmagazine.com. Archived from the original on 2020-08-06. Retrieved 2020-05-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Guardian Editorial Tribute to the Memory of Chike Obi (1921-2008)". waado.org. Archived from the original on 2020-01-27. Retrieved 2020-05-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "A Memorial Tribute for Professor Chike Obi by Edwin Madunagu". waado.org. Archived from the original on 2019-03-29. Retrieved 2020-05-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Chike Obi – Biography". Maths History (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-03. 
  5. "Igbo, Yoruba fight over maths". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-21. Retrieved 2020-05-17. 
  6. "Igbo, Yoruba fight over maths". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-21. Retrieved 2020-05-17.