Chima Nwosu jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin ti a bini 12, óṣu May ni ọdun 1986. Àrabinrin naa ṣere gẹgẹbi Defender fun Inneh Queens ni órilẹ ede naigiria[1][2]

Chima Nwosu
Personal information
Ọjọ́ ìbí12 Oṣù Kàrún 1986 (1986-05-12) (ọmọ ọdún 38)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2004Inneh Queens
National team
2004Nigeria women's national football team0 (?)(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Chima ti kopa ninu olympic ọdun 2004 gẹ̀gẹbi ọkan lara team awọn obinrin ti national lori bọọlu[3][4].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://fbref.com/en/players/e209ac9e/Chima-Nwosu
  2. https://www.olympedia.org/athletes/103012
  3. https://www.worldfootball.net/player_summary/chima-nwosu/frauen-olympische-spiele-2004-athen/nigeria-frauen-team/3/
  4. https://en-academic.com/dic.nsf/enwiki/473341