China Girl jẹ́ fíìmù ọdún 1987 kan, tó kún fún ìwúnilórí àti àhésọ, èyí tí Abel Ferrara jẹ́ olùdarí fún, tí Nicholas St. John tó jẹ́ alábàáṣiṣẹ́pọ̀ rẹ̀ kọ sílẹ̀.

China Girl
Fáìlì:China girl poster.jpg
Theatrical release poster
AdaríAbel Ferrara
Olùgbékalẹ̀Michael Nozik
Òǹkọ̀wéNicholas St. John
Àwọn òṣèré
OrinJoe Delia
Ìyàwòrán sinimáBojan Bazelli
OlóòtúAnthony Redman
OlùpínVestron Pictures
Déètì àgbéjáde
  • Oṣù Kẹ̀sán 25, 1987 (1987-09-25)
Àkókò89 minutes
Orílẹ̀-èdèUnited States
ÈdèEnglish
Ìnáwó$3.5 million[1]
Owó àrígbàwọlé$1,262,091[2] (USA)

China Girl jẹ́ fíìmù kan tó fẹ́ jọ ti Romeo and Juliet. Ìlú Manhattan ni ìbùdó-ìtàn, ìtàn náà sì dá lé ọ̀dọ́mọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tony láti ìlú Italy tó yófẹ̀ẹ́ pẹ̀lú ọ̀dọ́mọbìnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tye, láti ìlú Chinatown. Àmọ́ àwọn ẹ̀gbọ́nkùnrin àwọn méjèèjì níjà láàárín ara wọn, tí kì í ṣe kékeré.

Ìṣàgbéjáde

àtúnṣe

Wọ́n gbé fíìmù náà jáde ní September 25, ọdún 1987 ní tíátà mẹ́tàléláàádọ́wàá (193), wọ́n sì rí tó $531,362 lásìkò tí wọ́n gbe jáde.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "AFI|Catalog". 
  2. "China Girl". Box Office Mojo. 
  3. Rosenbaum, Jonathan. "China Girl". Chicago Reader. Archived from the original on October 30, 2013. Retrieved 25 March 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)