Chinaza Love Uchendu (tí wọ́n bí ní 3 December 1997) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó máa ń gbá bọ́ọ̀lù káàkiri àgbáyé, tó máa ń wà nípò agbedeméjì. Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Nigeria women's national football team.

Chinaza Uchendu
Personal information
OrúkọChinaza Love Uchendu
Ọjọ́ ìbí3 Oṣù Kejìlá 1997 (1997-12-03) (ọmọ ọdún 26)
Ibi ọjọ́ibíLagos, Nigeria
Ìga1.72 m (5 ft 7+12 in)
Playing positionMidfielder
Club information
Current clubGalatasaray
Number
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2017–2018Rivers Angels
2018–2020Braga
2020Linköpings FC1(0)
2022–2024Gyeongju KHNP0(0)
2024–Galatasaray0(0)
National team
2018–Nigeria
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọmọ-ẹgbẹ́

àtúnṣe

Uchendu gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ Rivers Angels ní Nigeria Women Premier League, láti ọdún 2017 wọ oṣụ̀ keje ọdún 2018. Lẹ́yìn náà ni wọ́n gbe lọ sí ìlú Portugal, pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Braga.[1]

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí

àtúnṣe

Lásìkò ìdíje Africa Women Cup of Nations ti ọdún 2018, Uchendu gba bọ́ọ̀lù fún eré àṣekágbà nìkan, níbi tí wọ́n ti mú ú wọlé ní ìsẹ́jú mẹ́jọ, kí eré náà tó parí. Ó ju bọ́ọ̀lù kan wọlé, èyí tó sì mú kí ẹgbẹ́ Nigeria women's national football team ó jáwé olúborí.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Super Falcon star Uchendu joins Braga from Rivers Angels". The Cable News. 26 July 2018. https://www.thecable.ng/uchendu-joins-braga-from-rivers-angels. Retrieved 22 December 2018. 
  2. "Nigeria Women vs South Africa Women". CAF Online. 1 December 2018. http://www.cafonline.com/en-us/competitions/totalwomenafconghana2018/matches/matchdetails?matchid=755a94af-d805-465a-a522-a669291d66cc. Retrieved 22 December 2018.