Chris Olukolade
Chris Olukolade (tí a bì ní Ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù kẹta, Ọdún 1959) jẹ́ ọ̀gágun àgbà tí ó jẹ́ agbẹnusọ fún ológun Nàìjíríà tí ó ti fẹ̀yìn tì. Òhun ni wọ́n yàn lẹ́yìn tí ọ̀gágun Brig Gen. Mohammed Yerima pàrí sáà rẹ̀. Wọ́n sí yàn ọ̀gágun Colonel Rabe Abubakar lẹ́yìn tí òhun náà parí sáà rẹ̀ bákan náà. Kí ó tó fẹ̀yìn tì ní ìpari ́ oṣù keje, ọdún 2015, ó jẹ́ alága fún ẹgbẹ́ Forum of Spokespersons on Security and Response Agencies (FOSSRA) in Nigeria.[1]
Chris Olukolade | |
---|---|
Agbẹnusọ fún ológun Nàìjíríà | |
In office March 19, 2013 – July 30, 2015 | |
Asíwájú | Brig Gen. Mohammed Yerima |
Arọ́pò | Col. Rabe Abubakar |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹta 1959 Idoani, Ìpínlẹ̀ Ondo, Nigeria |
Alma mater | Nigerian Defence Academy Obafemi Awolowo University |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Nigerian Army |
Years of service | 1982–2015 |
Rank | Major general |
Commands | 149 Infantry Battalion |
Battles/wars | Boko Haram Insurgency War, [peace keeping operations in Liberia, Sierra Leone & Sudan |
Ìgbà èwe rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Maj. Gen. Chris Olukolade ní Ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù kẹta, Ọdún 1959 sí ìlú Zaria, Ìpínlẹ̀ Kaduna , ṣùgbọ́n àwọ́n òbí rẹ̀ wa láti ìlúIdoani, ní Ipinle Ondo, Nigeria. Ó kàwé gboyè ní ilé ìwé yunifásitì Obafemi Awolowo University, Ile Ife ní ọdún 1983, ó sì darapọ̀ mọ́ ológún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní ọdún 1982. Wọ́n gbàá wọlé bíi ìgbákejì Lietenant látàrí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nígbà tí ó wà ní ipele kẹta gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ́ ológun. [2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Omonobi, ingsley (July 30, 2015). "General Chris Olukolade resigns as FOSSRA chairman". Abuja: Vanguard Newspaper. Archived from the original on April 29, 2016. https://web.archive.org/web/20160429223600/http://www.vanguardngr.com/2015/07/general-chris-olukolade-resigns-as-fossra-chairman/. Retrieved April 29, 2016.
- ↑ Ibeh, Nnenna (July 30, 2015). "Nigeria’s defence spokesperson, Olukolade, to launch books". Premium Times. Archived from the original on April 29, 2016. https://web.archive.org/web/20160429224733/http://www.premiumtimesng.com/news/more-news/185850-nigerias-defence-spokesperson-olukolade-to-launch-books.html. Retrieved April 29, 2016.