Christ Koumadje
Jean Marc Christ Koumadje (ti a bi ni ọjọ keje Oṣu Keje, 1996) jẹ agbabọọlu inu agbọn alamọdaju kan fun Alba Berlin ti Bundesliga Bọọlu inu agbọn .
Koumadje with Alba Berlin in May 2022 | |
No. 21 – Alba Berlin | |
---|---|
Position | Center |
League | Basketball Bundesliga EuroLeague |
Personal information | |
Born | 7 Oṣù Keje 1996 N'Djamena, Chad |
Nationality | Chadian |
Listed height | 7 ft 4 in (2.24 m) |
Listed weight | 269 lb (122 kg) |
Career information | |
High school | Montverde Academy (Montverde, Florida) |
College | Florida State (2015–2019) |
NBA draft | 2019 / Undrafted |
Pro playing career | 2019–present |
Career history | |
2019–2020 | Delaware Blue Coats |
2020 | Movistar Estudiantes |
2020–2021 | Avtodor |
2021–present | Alba Berlin |
Career highlights and awards | |
|
Koumadje with Alba Berlin in May 2022 | |
No. 21 – Alba Berlin | |
---|---|
Position | Center |
League | Basketball Bundesliga EuroLeague |
Personal information | |
Born | 7 Oṣù Keje 1996 N'Djamena, Chad |
Nationality | Chadian |
Listed height | 7 ft 4 in (2.24 m) |
Listed weight | 269 lb (122 kg) |
Career information | |
High school | Montverde Academy (Montverde, Florida) |
College | Florida State (2015–2019) |
NBA draft | 2019 / Undrafted |
Pro playing career | 2019–present |
Career history | |
2019–2020 | Delaware Blue Coats |
2020 | Movistar Estudiantes |
2020–2021 | Avtodor |
2021–present | Alba Berlin |
Career highlights and awards | |
|
Ile-iwe giga
àtúnṣeKoumadje gba bọọlu inu agbọn ile-iwe giga ni Ile- ẹkọ giga Montverde ni Montverde, Florida, nibiti o ti jẹ ẹlẹgbẹ pẹlu Ben Simmons .
Iṣẹ ile-ẹkọ giga
àtúnṣeKoumadje gba bọọlu inu agbọn kọlẹji ni Ipinle Florida . Lakoko akoko agba rẹ ni FSU, Koumadje ṣe aropin aaye 6.6 fun ere, atungba 5.6 fun ere, bulọọki 1.4 fun ere, ati ni iṣẹju 15.5 dun fun ere kan.
Iṣẹ Ọjọgbọn
àtúnṣeDelaware Blue Coats (2019–2020)
àtúnṣeLẹhin ti won ko riyan mo ara awon yiyan fun 2019 NBA, o fowo si iwe pẹlu Philadelphia 76ers . won ge nigba ibudó ikẹkọ ati pe a fi kun si iwe akọọlẹ ibudó ikẹkọ ati ṣi ti alaalẹ ti Delaware Blue Coats, alafaramo NBA G League ti 76ers. Koumadje ni ami mọkàndínlogun, atungba mewa, ati bulọọki marun ninu ifẹsẹwọnsẹ 114-107 pelu Raptors 905 ni ọjọ kerinla oṣu kejila. [1] Nl ọjọ kẹrin oṣu kinni, Ọdun 2020, Koumadje ṣe igbẹle ilọpo-mẹta ni ibori won ni 111-88 lori Long Island Nets, ti o ti fi ami mejila sile, atungba 16 ati igbasile oluranlowo bulọọki mejila kan. [2] Ninu ere mewa to kẹhin ti akoko ti won ge kuru 2019–20 G, Koumadje ṣe Ida aarin aaye 11.8, atungba 12.8, ati bulọọki 5.8 fun ere kan, jiju 66% lati aaye naa. O gba ami eye fun NBA G League Defensive Player ti Odun .
Movistar Estudiantes (2020)
àtúnṣeNi ọjọ kankanlelogun Oṣu Kẹsan, Ọdun 2020, Movistar Estudiantes kede pe wọn ti fowo si iwe pelu Koumadje.
Avtodor Saratov (2020–2021)
àtúnṣeNi Oṣu kejila ọgun'jo, Ọdun 2020, o ti fowo si iwe pẹlu Avtodor ti VTB United League . [3]
Alba Berlin (2021-bayi)
àtúnṣeNi ọjọ karundinlogbon Oṣu Keji, ọdun 2021, Alba Berlin kede pe wọn ti fowo si iwe pẹlu Koumadje titi di opin akoko 2022-23.
- ↑ "Sixers' Marial Shayok, Christ Koumadje lead Blue Coats to road win". December 14, 2019. https://sixerswire.usatoday.com/2019/12/14/sixers-marial-shayok-christ-koumadje-lead-blue-coats-to-road-win/.
- ↑ "Checking in on Sixers' Marial Shayok, the G League's top scorer; 7-foot-3 Christ Koumadje's triple-double and 'mean streak'". January 5, 2020. https://www.nbcsports.com/philadelphia/76ers/marial-shayok-sixers-nba-g-league-stats-christ-koumadje-triple-double-delaware-blue-coats.
- ↑ Empty citation (help)