Christiaan Barnard
Christiaan Neethling Barnard (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kọkànlá ọdún 1922, tí ó sì kú ní ọjọ́ kejì oṣù kẹsàn-án ọdún 2001) jẹ́ dókítà ọkàn àti àyà láti South Africa tí ó kọ́kọ́ fi ọkàn ènìyàn kan rọ́pò ti ẹlòmíràn nípa iṣẹ́ abẹ.[1][2] Ní ọjọ́ kẹta oṣù Kejìlá ọdún 1967, Barnard gbin ọkàn Denise Darvall tí ó kú lẹ́yìn ìjàmbá ojú ọ̀nà sí àyà Louis Washkansky.
Christiaan Barnard | |
---|---|
Barnard in 1972 | |
Ọjọ́ìbí | Christiaan Neethling Barnard 8 Oṣù Kọkànlá 1922 Beaufort West, Cape Province, Union of South Africa |
Aláìsí | 2 September 2001 Paphos, Cyprus | (ọmọ ọdún 78)
Ẹ̀kọ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 1950–2001 |
Gbajúmọ̀ fún | First successful human-to-human heart transplant |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 6 |
Àwọn olùbátan | Marius Barnard (brother) |
A bí Barnard ní Beaufort West, Cape Province, Barnard kọ́ nípa ìmọ̀ ìsègùn òyìnbó, ó sì ṣíṣe dókítà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ní South Africa.[3][4][5][6] Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ìdánwò tí ó ṣe lórí àwọn ajá, Barnard ṣe ìwárí àbáyọ sí àìsàn intestinal atresia. Àbáyọ yìí mú kí àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ mẹ́wàá yè Cape Town, èyí mú kí àwọn dókítà ní Britain àti United States bẹ̀rẹ̀ sí ma lọ ọ̀nà yìí.[7][8][9]
Ikú rẹ̀
àtúnṣeChristiaan Barnard fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kejì oṣù kẹsàn-án ọdún 2001 ní Paphos, Cyprus. Ọ̀pọ̀ ènìyàn rò pé àìsàn ọkàn ló yọrí sí ikú rẹ̀ ṣùgbọ́n ìwádìí padà fihàn pé Ásmà ló yọrí sí ikú rẹ̀.[10]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Organ Donation, GlobalViewpoints, Margaret Haerens editor, Detroit, New York, San Francisco, New Haven, Conn., Waterville, Maine, U.S.; London, England, UK: Greenhaven Press, 2013.
- ↑ The operation that took medicine into the media age, BBC, Ayesha Nathoo (Centre for Medical History, University of Exeter), 3 December 2017. The photo caption incorrectly states Louis Washkansky was the first heart transplant recipient, when in actuality he was second. Boyd Rush with physician James D. Hardy was the first person to receive a heart transplant in 1964.
- ↑ S Afr Med J, "A human cardiac transplant: an interim report of a successful operation performed at Groote Schuur Hospital, Cape Town", Barnard CN, 30 December 1967; 41(48): 1271–74.
- ↑ Every Second Counts: The Race to Transplant the First Human Heart, Donald McRae, New York: Penguin (Berkley/Putnam), 2006. See esp. Ch. 10 "The Wait" and Ch. 11 "Fame and Heartbreak", pages 173–214.
- ↑ Altman, Lawrence K. (3 September 2001). "Christiaan Barnard, 78, Surgeon For First Heart Transplant, Dies". The New York Times. https://www.nytimes.com/2001/09/03/world/christiaan-barnard-78-surgeon-for-first-heart-transplant-dies.html.
- ↑ Louis Washkansky (1913–1967) Archived 4 April 2017 at the Wayback Machine., Science Museum. Louis was born in Lithuania in 1913 and moved to South Africa in 1922.
- ↑ Calculated Risks: How to Know When Numbers Deceive You, Gerd Gigerenzer, Simon & Schuster, 2002.
- ↑ A Companion to Bioethics, Second Edition, Helga Kuhse, Peter Singer, Wiley-Blackwell, 2012.
- ↑ Every Second Counts, McRae, pages 176, 190.
- ↑ "Autopsy confirms asthma killed Barnard". Cyprus Mail. 5 September 2001. Archived from the original on 27 September 2007. https://web.archive.org/web/20070927202905/http://www.cyprus-mail.com/news/main_old.php?id=4655&archive=1.