Christie George (ti a bi ni ọjọ kewa osu kaarun ọdun 1984) je agbaboolu teleri omo Naijiria ti o n gba iwaju .

O jẹ ikan l'ara awon ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede awọn obinrin Naijiria ni Olimpiiki Igba ooru 2008 . [1]

Wo eyi naa

àtúnṣe
  • Naijiria ni Olimpiiki Igba ooru 2008

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Empty citation (help) 

Ita ìjápọ

àtúnṣe