Ìṣeọ̀rọ̀àsìkò

(Àtúnjúwe láti Chronology)

Ìṣeọ̀rọ̀àsìkò ni sayensi tito awon isele gegebi wo se sele ninu asiko, bi lilo asiko oriila. O tun je "wiwa bi isele se sele seyin".[1]

Ìṣeọ̀rọ̀àsìkò

Ìṣeọ̀rọ̀àsìkò je apa iseigba. Bakanna o tun je apa eko itan, bi itan aye, awon sayensi ile-aye, ati eko iwon asiko oniseorooriile.


  1. Memidex/WordNet, "chronology," memidex.com (accessed September 25, 2010).

Àdàkọ:Time Topics Àdàkọ:Chronology