Chuan Leekpai

Chuan Leekpai je Alakoso Agba ile Thailand tele. Chuan leekpai je oṣelu, o si je Aare ile agba Asofin ti ilu Thailand ati Agbenuso fun asofin lati odun 1992 si ojo kekandilogun, osu Ebibi odun 1997

Chuan LeekpaiItokasiÀtúnṣe