Chuks D General
Chuks D General ti órukọ a bisọ rẹ njẹ Chukwuyem Jude Israel jẹ alawada, host, radio presenter ati óṣèrè lọkunrin. Arakunrin naa gbajumọ lori awọn awada rẹ. Chuks jẹ óludari show ti awada to kó awọn gbajumọ ilẹ naigiria jọ lori idanilaraya. Chuks ni ójẹ alawada to pègèdè julọ ni Abuja. Óṣèrè lọkunrin naa da "Official Couple" silẹ; Èrè oritage naa ṣè afihan Anto Lecky(Ara awọn to kopa ninu idije Big Brother Naija)[1][2][3].
Igbèsi Àyè Àràkunrin naa
àtúnṣeChuks D General ni à bini ọjọ mẹ̀tadinlọgbọn, óṣu February ni Agbor, ipinlẹ Delta[4]. Ni ọjọ kẹrinlèèlógun, óṣu August ni ọdun 2019, Chuks fẹ Ngozi to wa lati Ipinlẹ Anambra[5].
Ẹkọ
àtúnṣeChuks lọsi ilè iwè ti Staff Model ni Agbor, Ipinlẹ Delta. Arakunrin naa jadè ni ilè iwè giga ti Ipinlẹ Nasarawa nibi to ti kẹẹkọ lori imọ statistics[6][7].
- ↑ https://keninfo.com.ng/2019/04/02/%EF%BB%BFchuks-d-general-biography-and-net-worth/
- ↑ https://authorityngr.com/2022/10/18/comedian-chuks-d-general-launches-talent-hunt-show/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-11-24. Retrieved 2022-11-24.
- ↑ https://www.modernghana.com/amp/nollywood/35701/nigeria-spontaneous-comedian-and-celebrity-event.html
- ↑ https://www.max1023.fm/comedian-chuks-d-generals-weds-ngozi-photo/
- ↑ https://dailytrust.com/my-biggest-fear-is-not-making-people-laugh-chuks-d-general/
- ↑ https://keninfo.com.ng/2019/04/04/chuks-d-general-biography-and-net-worth/