Chukwuemeka Fred Agbata

Chukwuemeka Fred Agbata Jnr. (tí a bí ní ọjọ́ Kẹ̀wá oṣù keje ọdún 1979) tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí CFA jẹ́ akọròyìn àti akàrọ̀yìn tẹ́lẹ̀ rí ní ile ìròyìn Channels TV.

Chukwuemeka Fred Agbata
Agbata ní oṣù kẹjọ ọdún 2023
Born10 Oṣù Keje 1979 (1979-07-10) (ọmọ ọdún 44)
Alma materEkiti State University
ShowTech Trends
Station(s)Channels TV
Time slotMondays 4:30 pm
ShowTech on Wheels with CFA
Station(s)Family Love FM Port Harcourt
NetworkFamily Love Radio Network
Time slot5:15–5:30 pm
CountryNigeria

Òun ni òlùdásílẹ̀ Pacer Venture ó sì ní ìbásepọ̀ pẹ̀lú Climate Action Africa.[1][2] Òun MD/CEO ilé iṣẹ́ "ICT Agency" ti Ìpínlẹ̀ Anambra.[3]

Èkọ́ rẹ̀ àtúnṣe

Agbata kàwé gboyè nínú ìmọ̀ sociology ní Yunifásítì Ìpínlẹ̀ EkitiAdo Ekiti, Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[4]

Iṣẹ rẹ̀ àtúnṣe

Ó jé olóòtú tẹ́lẹ̀ rí ní ilé ìròyìn Channels TV. Ní 2015, ó bẹ̀rẹ̀ ètò kán ní Channels TV tí àkòrí rẹ̀ jẹ́, Tech Trends,[5] wọ́n ma ń ṣe ẹtọ náà ní ọjọ́ Ẹtì.

Ní ọdún in 2015, ó bẹ̀rẹ̀ ètò kan lórí ẹ̀rọ rédíò tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ 'Tech on Wheels with CFA. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé iṣẹ́ ìròyìn rẹ́díò káàkiri Nàìjíríà ni ó ma ń gbé ètò náà sí wa orí afẹ́fẹ́ ní ọjọ́ rú. Díẹ̀ nínú àwọn ètò yìí ni 97.7 Love FM Port Halátiourt at 5.15–5.30pm; 104.5 Love FMníbuja at 6:30–àti5pm and 103.9 Love FM Uníahia at 7:30–7:45pm.[6]

Ní ọdún 2018, ó wà lára àwọn tí ó dá GoDoHub kalẹ̀, tí àwọn míràn tún mọ̀ sí GoDo.ng kalẹ̀.[7][8][9][10][11]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Eleanya, Frank (2019-03-28). "Founder Institute targets pre-fund startups as it launches in Nigeria". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-24. 
  2. Ovat, Michael (2023-09-09). "Climate Action Africa reiterates mission to ensure resilience on continent". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-24. 
  3. Nwanodu, Angela (2023-05-24). "Anambra State Government Partners the Church for Technological Transformation - Anambra State Ict Agency" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-04. 
  4. Oluka, Peter (2023-08-29). "Meet Chukwuemeka Fred Agbata, "CFA" - The Man Behind Anambra's Technology Revolution". Techeconomy (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-23. 
  5. "Tech firm to give N10m to young entrepreneurs - Daily Trust". dailytrust.com. Retrieved 2023-09-11. 
  6. Comms Week (21 June 2015). "Tech on Wheels with CFA Debuts on Family Love FM Radio Network". Nigeria Communications Week. https://nigeriacommunicationsweek.com.ng/tech-on-wheels-with-cfa-debuts-on-family-love-fm-radio-network/. Retrieved 20 June 2019. 
  7. "GoDo Hub launches in Lagos, to help Start-ups develop - Nigeria internet Registration Association (NiRA)". 
  8. Ramoni, Rasikat (15 December 2017). "Tech firm to give N10m to young entrepreneurs". Daily Trust. Archived from the original on 15 December 2017. https://web.archive.org/web/20171215051859/https://www.dailytrust.com.ng/tech-firm-to-give-n10m-to-young-entrepreneurs.html. Retrieved 14 June 2019. 
  9. "Tech Trends – Channels Television". 
  10. "GoDo.ng Facility for Startup Development Debuts - THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2023-09-11. 
  11. Rapheal (2019-03-28). "Silicon Valley-based company to support 20 Nigerian startups". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-11.