Chuma_Mmeka,_May_2009

Chuma Mmeka ti a tun pè ni 'T-char' jẹ óṣèrè lọkunrin ti Nollywood. Arakunrin naa tun jẹ ólukọwè ati ẹni to fẹran lati ma ran awọn ọmọdè lọwọ[1].

Igbèsi Àyè Àrakunrin naa àtúnṣe

Chuma ni a bini ọjọ kejileelógun, óṣu June ni ọdun 1975 fun Enyi Jim I. Mmeka ati Lolo Jossy C. ni Amaigbo ni ijọba ibilẹ ti Nwangele ni ipinlẹ Imó[2][3].

Chuma bẹrẹ sini kọ ewi lati igba toti wa ni ọmọ ọdun mẹjọ[4].

Chuka fẹ Nikky Mmeka ti wọn si bi ọmọ fun ara wọn[5]. Óṣèrè lọkunrin naa pada nu iya rẹ ni óṣu May ọdun 2018 ati baba rẹ ni óṣu january ọdun 2019[2].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla àtúnṣe

Óṣèrè lọkunrin naa gba ẹbun gẹgẹbi ẹni to pegede ninu Ewi ti awọn ọmọdè ti Maryam Babangida ni ilẹ Naigiria nigba to pè ọmọ ọdun mẹtala[6].

Ni ọdun 2019, Chuma ba ami ẹyẹ ti óṣèrè guild ti ilẹ Naigiria[7].

Itọkasi àtúnṣe

  1. https://keninfo.com.ng/2020/11/14/chuma-mmeka-biography-and-net-worth/
  2. 2.0 2.1 https://www.manpower.com.ng/people/15952/chuma-mmeka
  3. https://books.google.com.ng/books/about/Echoes_of_the_Mind.html?id=24QqjwEACAAJ&redir_esc=y
  4. https://dailyreviewonline-ng.com/2016/01/15/book-review-the-broken-home-a-poetic-inside-story-by-chuma-mmeka/
  5. https://www.amazon.com/Chuma-Mmeka/e/B015DDWZJM%3Fref=dbs_a_mng_rwt_scns_share
  6. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-11-22. Retrieved 2022-11-22. 
  7. https://www.sojworldnews.com/imo-state-agog-as-nollywood-celebrates-20th-anniversary-of-actors-guild-of-nigeria-in-grand-style-see-photos/