Citrus australis
Taxonomy not available for Citrus; please create it automated assistant
Citrus australis, ti Dooja, ọsàn wẹrẹ, ọsàn wẹrẹ Australian tàbí ọsàn wẹrẹ Australian je igi ńlá tàbí igi kékeré tí ó pèsè èso jije. Ó wà ní agbègbè Beenleigh àti ní àríwá ní Queensland, Australia.[1][2]
Australian round lime | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Irú: | Template:Taxonomy/CitrusC. australis
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Template:Taxonomy/CitrusCitrus australis |
Citrus australis jẹ́ igi tí ó tó ni gíga. Èso rẹ dàbí ọsàn wẹrẹ tàbí jo àwọ̀ píà, pẹ̀lú àwọ̀ ewé tàbí àwọn yẹ́lò àti àwọn ewé tí kò wo baibai. Ìwé tí 1899 The Useful Native Plants of Australia ṣe àkíyèsí pé "èso rè tí ó jẹ́ ìwọ̀n ẹyọ kan àti àbọ̀ ní alaja, ní ọdọọdún,ó' máa mú gbèdéke ohun mímu láti ọtí rẹ̀."[3]
Australian limes |
| |||||||||||||||||||||||||||||||||
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Planchon, Jules Émile. 1858. Hortus Donatensis 18, Citrus australis
- ↑ "Citrus australis (RUTACEAE) Native lime, Round lime". Save our Waterways Now. Retrieved 2007-08-06.
- ↑ Maiden, J. H. (1889). The useful native plants of Australia: Including Tasmania. Turner and Henderson, Sydney. https://primo-slnsw.hosted.exlibrisgroup.com/primo-explore/fulldisplay?docid=SLNSW_ALMA21105097830002626&context=L&vid=SLNSW&search_scope=EEA&tab=default_tab&lang=en_US.