Claude Haffner (tí wọ́n bí ní ọdún 1976) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Fráǹsì àti Kóngò. Ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ tó fi mọ́ Ko Bongisa Mutu, Défilé Célianthe àti Noire ici, blanche là-bas.

Claude Haffner
Orúkọ àbísọكلود هافنر
Ọjọ́ìbí1976 (ọmọ ọdún 48–49)
Kinshasa, Congo Republic
Orílẹ̀-èdè
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Director, production manager, screen writer, actress
Ìgbà iṣẹ́2000–present
Parents
  • Pierre Haffner (father)
  • Sudila Mwembe (mother)
Àwọn olùbátanFrédéric Haffner (brother)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe