Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nàìjíríà

(Àtúnjúwe láti Coat of arms of Nigeria)

Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nàìjíríà ni asa dudu pelu ila funfun meji ti won tenu po bi Y. Awon wonyi duro fun odo nla meji ni Naijiria: Odò Benue ati Odò Niger.

Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ọ̀pá àṣẹNàìjíríà
MottoUnity and Faith, Peace and Progress