Cocada amarela
Cocada Amarela jẹ́ oúnjẹ ìpanu ìbílẹ̀ Angola tí a sè pẹ̀lu ẹyin àti àgbọn.[1] Ó ní àwọ̀ pupa èyi tí ó jẹ́ bẹ́ẹ̀ nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹyin tí wọ́n lò láti sè é.[2][3] Orúkọ rẹ̀, Cocada Amarela, túmọ̀ sí Cocada tí ó pupa.[4]
Cocada amarela with some cinnamon powder in a glass bowl | |
Type | Dessert |
---|---|
Place of origin | Angola |
Main ingredients | Eggs, coconut |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Nítorí ìtàn ìmunisin Angola, Cocada Amarela jẹ́ èyí tí ó jọ àwọn ìpanu ilẹ̀ Portuguese, èyí tí a mọ̀ fún ìlò ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹyin pupa nínú oúnjẹ ìbílẹ̀ wọn.[4]
Àwọn Èròjà
àtúnṣe- Àgbọn wẹ́wẹ́
- Iyọ̀
- Omi
- Ṣúgà
- Ẹyin [5]
Tún wo
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Margarita's International Recipes: Angolan - Cocada Amarela
- ↑ Roufs, Timothy G.; Roufs, Kathleen Smyth (2014). Sweet treats around the world: an encyclopedia of food and culture. Santa Barbara, California: ABC-CLIO. ISBN 978-1-61069-220-5.
- ↑ "Cocada amarela | Traditional Pudding From Angola | TasteAtlas". www.tasteatlas.com. Retrieved 2024-04-11.
- ↑ 4.0 4.1 Newman, Mary; Kirker, Constance L. (April 5, 2022). Coconut: A Global History. Reaktion Books. ISBN 9781789145267.
- ↑ Cocada amarela