Cole Shade Sule

Cole Shade Sule (ti a bi ni ọjọ karun ni Oṣu kọkanla ọdun 1980) jẹ oluwe ómí tẹlẹri lati orilẹ-ede Kamẹru , ti o je elere idaraya ni isọri-sprint. Sule yege fun 50 m freestyle awọn ọkunrin ni Olimpiiki Igba ooru 2004 ni Athens, nipa gbigba ogbontarigi Ami eye Kan lati FINA, ni akoko iwoleti 25.96. [1] O koju awọn oluwẹiwẹ meje miiran ninu ooru mẹta, pẹlu Chris Hackel, eni omo ọdun merindinlogun ti orilẹ-ede Mauritius. O sare si ipo keji kere ju 0.17 ti iṣẹju kan lẹhin olubori Hackel ni 26.16. Sule kuna lati lọ siwaju si ipele semifinals, bi o ti gbe erinlelogota ninu 86 odo ninu ìdíje igbaradi fun ìdíje. [2]

Awọn itọkasiÀtúnṣe