Colin Maclaurin
Colin Maclaurin (1698 - 14 June, 1746) ni ojogbon ti o kere ju lo. omo odun mokandinlogun ni nigba ti o di ojogbom matimatiiki ni Marischa College ni Aberdeen ni Scotland ni Ogbon-ojo osu kesan-an odun 1717. Leyin eyi ni o lo di ojogbon Matimatiiki ni Edinburgh ni scotland ni 1725. Sir Isaac Newton ni o ni ki won so o di ojogbon nibe.
Colin Maclaurin | |
---|---|
Colin Maclaurin (1698–1746) | |
Ìbí | February, 1698 Kilmodan, Cowal, Argyllshire, Scotland |
Aláìsí | June 14, 1746 Edinburgh, Scotland |
Ibùgbé | Scotland |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Scottish |
Pápá | Mathematician |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Aberdeen University of Edinburgh |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Glasgow |
Academic advisors | Robert Simson |
Notable students | Robert Adam |
Ó gbajúmọ̀ fún | Euler–Maclaurin formula Maclaurin's inequality |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Académie des Sciences, Grand Prize |
Religious stance | Presbyterian |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |