"Ìrẹsì Aláṣẹ̀pọ̀" tí wọ́n ń pè ní Concoction Rice jẹ́ oúnjẹ kan tí ó jé oúnjẹ ilé Nàìjíría tí wón a máa ṣe dípo JOLLOF rice tabi Ìrèsì lásán. Àwọn èròjà tí wọn máa fi ni ṣe náà ni : Ìrèsì, Epo pupa, Iyọ, Àlùbósà, Ata, àti àwọn ohun ẹlẹ́ẹ̀mí méje bíi, Edé àti Ẹja yiyan,. Ṣùgbọ́n ìdí tí wọn fí ń pé ní Aláṣẹpọ ni pé Èpò pupa ni wøn fí ń ṣe òhun èyí tí o yatọ sí òróró tí wọn fí ń ṣe JOLLOF rice. [1][2]

Jollof Rice and fried plantain with diced-beef sauce and cucumber

Àwọn èròjà míràn tí wón fí ń ṣe Ìrèsì aláṣẹpọ ni: Efirin, Kori, Irú, Ata, Maagí, Àlúbósà. Ìrèsì aláṣẹpọ tí jìnà nígbà tí omi inú rere bá gbé yanyan. [3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Traditional Way To Prepare Rice". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-16. Archived from the original on 2022-10-14. Retrieved 2022-07-01. 
  2. Onyeakagbu, Adaobi (2021-12-09). "Everybody should know how to make this concoction rice". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-01. 
  3. "How To Make Native Jollof Rice". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-06-28. Archived from the original on 2022-07-01. Retrieved 2022-07-01. 
  4. "Concoction rice". ResearchGate. https://www.researchgate.net/publication/322301602_Preliminary_Survey_of_Local_Herbs_Used_in_Concoction_for_Herbal_Rice_Preparation.