Cornelius Olaleye Taiwo (tí wọ́n bí ní 27 November ọdún 1910, tí ó sì kú ní 8 April 2014) jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Nàìjíríà, tó jẹ́ onímọ̀, agbẹjọ́rò àti òǹkọ̀wé.

Omoba
Cornelius Olaleye Taiwo
Ọjọ́ìbí(1910-10-27)27 Oṣù Kẹ̀wá 1910
Oru-Ijebu Ogun State, Nigeria
Aláìsí8 April 2014(2014-04-08) (ọmọ ọdún 103)
Ikeja, Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Cambridge
University of London
Iṣẹ́Educator, lawyer, author

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Taiwo ní 27 October 1910, sí Oru-Ijebu ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní Nàìjíríà, sínú ìdílé Isaac àti Lydia Taiwo.[1] Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní St. Luke's School, tó jẹ́ ilé-ìwẹ́ CMS ti St. Luke's Church lẹ́yìn ogun àgbáyé kìíní, ní Oru, Ijebu ní ọdún 1921. Lẹ́yìn náà ni ó lọ sí St Andrews College, ní Oyo, kí ó ṣẹ̀ tó lọ Yaba Higher College, Lagos. Ó tún kàwé ní University of London, níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí D. Litt ní ọdún 1982. Bákan náà ni ó gba oyè M.A nínú ẹ̀kọ́ ìṣirò Mathematics láti Trinity College, Cambridge University, oyè Barrister-at-Law ní Middle Temple Inn's Court àti oyè Hon. LL.D. (Cape Coast).[2]

Ìdálọ́lá

àtúnṣe
  • Baba Ijo -oyè ní St. Luke's Church, ní Oru, Ijebu láti ọdún 1973.
  • Fellow of Commonwealth Council for Educational Administration
  • Fellow of Nigerian Academy of Education
  • Lord LUPEN; NAPE's highest award (the Lord of all Luminaries of Professional Educators of Nigeria, 1989)
  • Inducted into the International Educators' Hall of Fame

Àọn ìwẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Lára àwọnìwé tó ti kọ ni;

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Deji-Folutile, Olabisi; Babalola, Ademola (27 October 2010). "100 years today...Prof. C. O. Taiwo tells his story". hoofbeat. Archived from the original on 6 January 2014. Retrieved 19 November 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Homepage". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-09.