Cornus mas
Cornus mas, ni a tun mo sí cornel (a tun le pe ni Cornelian cherry, European cornel or Cornelian cherry dogwood), je eya shrubu tabi eya igi kekere ninu idile dogwood Cornaceae ti o tan mo Western Europe, Southern Europe, ati Southwestern Asia.
Cornelian cherry | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Irú: | Template:Taxonomy/CornusC. mas
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Template:Taxonomy/CornusCornus mas | |
Distribution map | |
Synonyms | |
Synonymy
Cornus erythrocarpa St.-Lag.
Cornus flava Steud. Cornus homerica Bubani Cornus mascula L. Cornus nudiflora Dumort. Cornus praecox Stokes Cornus vernalis Salisb. Eukrania mascula (L.) Merr. Macrocarpium mas (L.) Nakai |
Àpèjúwe
àtúnṣeEyi je shrubu ti o ga jù sí èyí ti o Tobi tabi igi kekere ti o dagba ni giga to metre máàrún sí méjìlá pẹlu eka ti o je awo Brown sí awo ewe. Ewe re keyin sí ara wọn,bi centimeter merin sí mewa ni gigun ati centimeter meji sí mẹrin ni fífẹ, pẹlú ovate sí awo oblong ati gbogbo ara re. Ododo rẹ jẹ kekere bi diameter máàrún sí mewa pẹlu ofeefe petali merin,ti a ṣẹda papo ni mewa sí ogún o le máàrún ni winter ti o ti pe laarin feburary ati marchi ni UK,[1] ki ewe naa to farahan. Eso yìí jé oblong drupe pupa bi centimeter meji ni gigun sí 1.5cm ni diamita,o sì ni eso kan ninu.
Awọn Atokasi
àtúnṣe- ↑ Nicholson, B. E.; Wallis, Michael (1963). The Oxford Book of Garden Flowers. London: Oxford University Press. ISBN 1-131-80240-3.