Cristela Alonzo

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Cristela Alonzo jẹ́ apanilẹ́rìn-ín, òṣèrébìnrin, òǹkọ̀wé àti aṣàgbéjáde eré, tó ṣàfihàn nínú ABC sitcom Cristela.[1] Èyí mu kó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ láti Mexico tó máa kọ́kọ́ ṣẹ̀dá, ṣàgbéjáde, àti kọ eré apanilẹ́rìn-ín kan.[2][3]

Cristela Alonzo
Alonzo at the PaleyFest preview for Cristela
ÌbíJanuary 6 Àdàkọ:Birth based on age as of date
MediumStand-up, television, film
Years active1995–present
GenresObservational comedy, blue comedy, physical comedy, surreal humor, satire
Subject(s)Latin American culture, everyday life, sex, racism, social awkwardness
Ibiìtakùncristelaalonzo.com

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Dominus, Susan (October 17, 2014). "Cristela Alonzo Wants to Make America Laugh". The New York Times. https://www.nytimes.com/2014/10/19/magazine/cristela-alonzo-wants-to-make-america-laugh.html. 
  2. Fernandez, Maria Elena (October 10, 2014). "All Jokes Aside, Cristela Alonzo Makes TV History". NBC News. https://www.nbcnews.com/pop-culture/tv/all-jokes-aside-cristela-alonzo-makes-tv-history-n221576. 
  3. Hinojosa, Maria (October 24, 2014). "Cristela". Latino USA (NPR). https://www.npr.org/2014/10/24/358644879/cristela.