Cross River National Park

Cross River National Park jẹ́ pápá ìṣeré kan ní Ìpínlẹ̀ Cross River, Nàìjíríà. Ó pín sí apá méjì, apá Okwangwo (tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 1991) àti apá Oban (tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 1988). Ilẹ̀ rẹ̀ tó 4,000 km2, púpọ̀ nínú rẹ̀ sì kún fún igbó, pàápàá jùlọ ní àríwá, àárín pápá ìṣeré náà, àti apá pápá ìṣeré náà tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò. Apá kan pápá ìṣeré náà wà lábẹ́ ìdarí ìjọba Congo.[1]

Bákan náà, pápá yìí jẹ́ ilé fún oríṣríṣi ẹranko, [2] àwọn ẹranko bi common chimpanzees, drills àti Cross River gorillas.[3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named NNPS
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Terborgh2002
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named BirdlifeOban
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named BirdlifeOkwangwo