Curaçao (pípè /ˈkjʊərəsaʊ/; Duki: [Curaçao] error: {{lang}}: text has italic markup (help), Papiamentu: Kòrsou) je erekusu ni apaguusu Omi-okun Karibeani, nitosi etiomi Venezuela. Erekusu Ileagbegbe Curaçao[1] (Dutch: Eilandgebied Curaçao, Papiamentu: Teritorio Insular di Kòrsou), to lamupo mo erekusu gbangba na ati ereku Klein Curaçao ("Curaçao Kekere"), je ikan ninu awon erekusu ileagbegbe Netherlands Antilles, nipa bayi o je apa kan Ileoba awon Nedalandi. Oluilu re ni Willemstad.

Erekusu Ileagbegbe Curaçao
Island Territory of Curaçao
Eilandgebied Curaçao
Teritorio Insular di Kòrsou
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèHimno di Kòrsou
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Willemstad
12°7′N 68°56′W / 12.117°N 68.933°W / 12.117; -68.933
Èdè àlòṣiṣẹ́ Dutch, Papiamentu, English and Spanish
Ìjọba See Politics of the Netherlands Antilles
 -  Prime Minister of N.A. Emily de Jongh-Elhage
 -  Governor of N.A. Frits Goedgedrag
 -  Administrator Lizanne Dindial
Constitutional monarchy part of the Netherlands Antilles 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 444 km2 
171.4 sq mi 
Alábùgbé
 -  2009 census 141,766 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 319/km2 (ranked as part of N. A.)
821/sq mi
Owóníná Netherlands Antillean guilder (ANG)
Àkókò ilẹ̀àmùrè -4 (UTC-4)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .an
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 599

Àwọn Akóìjánupọ̀: 12°11′N 69°00′W / 12.183°N 69°W / 12.183; -69

ItokasiÀtúnṣe

  1. English name used by government of Curaçao and Government of Netherlands Antilles (English is official language of Netherlands Antilles and Island Territory of Curaçao)