Túndé Mákindé Tòkunbọ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Dẹ̀jọ Túnfúlù jẹ́ gbajúgbajà òṣèré orí ìtàgé tí a bí ní ojọ́ Kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Karùnún ọdún 1969 (31-05-1969), sí ìdílé ọ̀gbẹ́ni Abbas Mákindé ní ìlú Abẹ́òkúta. [1][2][3]

Dẹ̀jọ Túnfúlù
Ọjọ́ìbíTúndé Mákindé Tòkunbọ̀
ojọ́ Kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Karùnún ọdún 1969
Abẹ́òkúta
Iṣẹ́òṣèré orí ìtàgé

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Yoruba Actor,Kunle Tokunbo AKA Dejo Tunfulu Marries His Fiance, Deola Idowu Gunwa In Lagos". Gistmania (in Èdè Ruwanda). Retrieved 2019-12-11. 
  2. "What Is Happening Between Lizzy Anjorin And Dejo Tunfulu?". P.M. News. 2011-07-11. Retrieved 2019-12-11. 
  3. "Popular Yoruba Actor, Dejo Tunfulu Marries Off His 17 Year Old Daughter". Nigerian Celebrity News + Latest Entertainment News. 2016-05-31. Archived from the original on 2019-12-11. Retrieved 2019-12-11.