Dabo Aliyu

Olóṣèlú

Olùrànlọ́wọ́ Ìǹspẹ́kítọ̀ Gbogbogbò ti ọlọ́pàá (fẹ̀hìntì) Dabo Aliyu CON mni psc jẹ́ Alákoso ìjọba ní ìpínlẹ̀ Anambra láti Oṣù kọkànlá sí Oṣù kejìlá ọdún 1993, ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí àbojútó ìpínlẹ̀ Yobe láti Oṣù kejìlá ọdún 1993 sí Oṣù kẹjọ ọdún 1996 ní àkókò ìjọba ológun ti General Sani Abacha. Ó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ Olùdárí NSO State House Annex nígbà kan, ó tún jẹ́ Ìrànlọ́wọ́ Ìǹspẹ́kítọ̀ Gbogbogbò ti ọlọ́pàá ti agbègbè Zone 7 Abuja. A fún un ní àmì-ẹ̀yẹ lórí Ìdènà àwọn ìwà burúkú, ẹ̀bùn lórí Kọmísọ́nà ọlọ́pàá tí ó dára jùlọ nípasẹ̀ Olùyẹ̀wò Gbogbogbò ti ọlọ́pàá àtí ẹ̀bùn lórí iṣẹ́ ọlọ́pàá tó dára jùlọ ní Ìpínlẹ̀ Anambra. Ó ń gbé ní Ìpínlẹ̀ Kaduna, ó jẹ́ Sardaunan Ruma àkọ́lé ní ìlú abínibí rẹ̀, Ruma.[1]

Dabo Aliyu
Fáìlì:Portrait of Dabo Aliyu in uniform.jpg
Governor of Anambra State
In office
November 1993 – December 1993
AsíwájúChukwuemeka Ezeife
Arọ́pòMike Attah
Governor of Yobe State
In office
14 December 1993 – 14 August 1996
AsíwájúBukar Abba Ibrahim
Arọ́pòJohn Ben Kalio
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kejìlá 1947 (1947-12-29) (ọmọ ọdún 76)[citation needed]
Batsari - Kastina State[citation needed]
Aláìsí13 December 2020(2020-12-13) (ọmọ ọdún 72)
(Àwọn) olólùfẹ́Khadija Dabo Aliyu

Àwọn Ìtọ́ka Sí àtúnṣe

  1. "Nigerian States". WorldStatesmen. Retrieved 2010-01-04.