Dabo kolo
Dabo kolo (Amharic: ዳቦ ቆሎ (d'abo kolo), Oromo: Boqqolloo daabboo) jẹ́ oúnjẹ ìpanu ní ilẹ̀ Ethiopia.[1][2][3] Dabo kolo túmọ̀ sí búrẹ́dì alágbàdo ní èdè Amharic, tí dabo dúró fún búrẹ́dì, nígbà tí kolo dúró fún àgbàdó tàbí barley sísun, chickpeas, sunflower seeds, àti àọn èròjà ìbílẹ̀ mìíràn.[4]
Dabo kolo ( ዳቦ ቆሎ ) | |
Region or state | Ethiopia, Eritrea, Democratic Republic of the Congo |
---|---|
Main ingredients | Flour, milk, barley |
Other information | For snacking or festivity |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Búrẹ́dì Kolo tí wọ́n wé mọ́ pépà jẹ́ èyí tí wọ́n máa ń tà ní àdúgbò. Tí wọ́n bá fẹ́ sè é, wọ́n máa dín dough tí wọ́n gé lára èyí tí wọ́n yí pọ̀. Nígbà mìíràn, wọ́n máa ń fi oyin si kí dabo kolo ba lè dùn dáadáa. Dabo kolo tún jẹ́ oúnjẹ ìlú Congo bákan náà.[5] Ohun mìíràn tí a lè fi ṣe dabo kolo ni coffee beans.[6]
Ayẹyẹ ṣíṣe
àtúnṣeDabo kolo jẹ́ oúnjẹ kan tó yàtọ̀ lásìkò ayẹyẹ ọdún tuntun àwọn Ethiopia. Àwọn Beta Israel (Àwọn ará Júù ti ilẹ̀ Ethiopian) máa ń pin lásìkò ti wọ́n ń jẹ oúnjẹ Shabbat.[7]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Dabo Kolo. Traditional Snack From Ethiopia". www.tasteatlas.com. Retrieved 27 May 2021.
Dabo kolo is an Ethiopian snack with a spicy flavor and crunchy texture, consisting of flour, sugar, salt, water, butter, and berberé spices.
- ↑ Àdàkọ:YouTube. Transliterated Amharic: Yemit’adi dabo k’olo āserari. A lady explains how to prepare Dabo kolo with ingredients of turmeric and berbere for colour, sugar, oil, milk, water and wheat flour. Video of 45m 56s. Retrieved 27 May 2022.
- ↑ Àdàkọ:YouTube. Ingredients are hot water, salt, sugar, oil, and colouring. The dough is kneaded to a long roll, then cut to small pieces of sweetcorn size, and fried in hot oil for 3 minutes. Video of 1m 51s. Retrieved 27 May 2022.
- ↑ "Kolo. Traditional Snack From Ethiopia - TasteAtlas". www.tasteatlas.com. Retrieved 27 May 2022.
Kolo is a traditional Ethiopian snack consisting of a combination of roasted grains such as barley, chickpeas, and sunflower seeds.
- ↑ Kanjilal, Sahana (26 November 2019). "Top 9 Congolese Foods for Your Appetite". flavorverse.com. Retrieved 27 May 2022.
- ↑ The Hans India (15 January 2018). "Telangana International Sweets Festival proves to be a big hit". www.thehansindia.com. Retrieved 27 May 2022.
- ↑ Marks, Gil (1996). The World of Jewish Cooking. New York, NY: Simon & Schuster. p. 273. ISBN 9780684835594. https://books.google.com/books?id=Ux2lGKCKVPYC&q=The:+World+of+Jewish+Cooking.