Dahiru Musdapher (ojoibi 15 July 1942 ni Babura Town, Ipinle Jigawa, Nigeria) ni Oludajo Agba Ileejo Gigajulo ile Naijiria lati 2011 de 2012.

Dahiru Musdapher
12k Oludajo Agba ile Naijiria
In office
29 August 2011 – 15 July 2012
AsíwájúAloysius Iyorgyer Katsina-Alu
Arọ́pòAlooma Mariam Mukhtar
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí15 Oṣù Keje 1942 (1942-07-15) (ọmọ ọdún 82)