Dame Portugaise (d. lẹyin 1634), jẹ oniṣowo ẹru Nhara ilẹ Afrika. Arabinrin naa jẹ ọmọbinrin ọkunrin ilẹ Portuguese ati arabinrin ilẹ Afrika. Dame da oko owo ẹru silẹ ni Rufisque nibi o ti jẹ alagata ti wọn maa n pe larin awọn oludari ilẹ Portuguese ati Afrika latari ẹya awọn obi rẹ̀. Eyi jẹ ki Dame dari owo ṣiṣè larin agbegbe mejèèji[1]. Dame jẹ ọkan lara awọn obinrin óniṣowo ati alagata lari Awọn ẹya Europe ati Afrika titi di ẹyin century ti ọkan dinlogun[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. "Dame Portugaise: The Luso-African Female Slave Trader Who Acted as a Liaison Between African Chiefs and Europeans in 17th-Century Senegal". Flipboard. 2023-03-30. Retrieved 2023-08-26. 
  2. Hafkin, N.; Bay, E.G. (1976). Women in Africa: Studies in Social and Economic Change. Studies in Social and Economic Change. Stanford University Press. p. 20. ISBN 978-0-8047-6624-1. https://books.google.com.ng/books?id=pWffQVU85ccC&pg=PA20. Retrieved 2023-08-26.