Daniel Francisco (ti a bi ni ọjọ Kẹjo ọsu keji ọdun 2000) jẹ oluwe-odo fun orilẹ-ede Angola . O dije ninu ìdíje oni labalaba mita 50 ti awọn ọkunrin ni idije Aquatics World 2017 . [1] Ni ọdun 2019, o ṣe aṣoju Angola ni ere Afirika 2019 ti o waye ni Rabat, Morocco. [2]

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Empty citation (help) 
  2. Empty citation (help)